PROGRAMMES:
Etò
CITIZENS CLUSTER– this is a virtual or physical meeting platform created for residents within a community to foster discussions and engagement in community development issues.
CIVIC OUTREACH– Organised talks, meetings, and symposiums for groups, families, and institutions to serve as enlightenment vehicles.
CITIZENS EMPOWERMENT– Helping community members develop business and vocational ideas and have access to start-up capitals and venture capitals.
ÌWÀPÒ ỌMỌ ÌLÚ– Èyí ni ìpele ìpàdé tí ayélujára àti ti ara tí adá fún olùgbé nínú agbègbè kan láti múkí ìjíròrò àti ìkópa nínú àwọn ọ̀rọ̀ ìdàgbàsókè agbègbè ṣelẹ̀.
ÌJÁDE ÌṢÈLÚ- ọ̀rọ̀ tí a sètò, ìpàdé, àpérò fún ẹgbé, ẹbí, ìgbékalẹ̀ láti dúró bíi okọ̀ ìtalọ́yẹ.
RÓNILÁGBÁRA ARÁ ÌLÚ- Ríran ará ìlú lọ́wọ́ láti dá òkòwò àti èrò iṣé ọwọ́ àti láti ní ànfààní sí owó ìbẹ̀rẹ̀ òwò àti Olùwádìí ìṣòwò.
