WHO WE ARE eni tí ajé

WHO WE ARE:


MISSION: Enlightening and empowering people towards achieving a better community.

VISION: To awaken and raise the consciousness of a people to their rights and responsibilities through a platform of citizen engagement and education.

ENI TÍ AJẸ́:


IṢÉ ÀPÍNFÚNNI: Ìtanilọ́yẹ àti ríró àwọn ènìyàn ní agbára láti ní àwùjọ tí ódára jùlọ.

ÌWÒYE: Fún ìtanijí àti sísọ ìmọ ohun àwọn ènìyàn kan sókè sí ẹ̀tọ́ àti ojúúṣe wọn nípasẹ̀ ònà ìsàlù ìsèdúró àti ẹ̀kọ́ ará ìlú.

WHO WE ARE:
We understand that building responsive and accountable states without recognizing and supporting the contributions of organized citizens will do little to promote sustainable change. Rights claims are socially and politically transformative, and citizen engagement can strengthen accountability frameworks and bolster state capability. For example, social movements create and hold open democratic spaces that create possibilities for reformers within the state to change and implement policy, and from these, the benefits of citizen action accumulate over time.

We are dedicated to actively engaging the residents of the southwest geopolitical region of Nigeria in addressing consumer, environmental, economic, and social justice issues. We conduct research, training, and educational activities in support of this mission. We join with members, partners, allies, and friends to create more just, equitable, and sustainable communities within the region. We do this by taking action at the local, state, and national levels – calling for a fair & just economy, affordable quality health care, citizens’ rights, and respect.

ENI TÍ AJẸ́:
Óyé wa wípé kíkọ́ ìpínlẹ̀ tí ó ní ìdáhùn atí ìjéèrísí láìsí ìdánimọ̀ àti àtìlẹyìn fún àfikún àwọn ọmọ ìlú tí óní ètò yóò ṣe díẹ̀ láti gbé ìyípadà tí ó seé múdúró lárugẹ. Gbígba ẹ̀tọ́ jẹ́ ìyípadà ní àwùjọ àti àkóso, àti ìsèdúró ará ìlú le mú ìlànà ìjéèrísí àti se àtìlẹyìn agbara  ìlú. Fún àpẹẹrẹ, ìṣípòpadà àwùjọ dá àti mú ààyè àwaarawa tí ó dá ìṣeéṣe fún àwọn alátúntò ní ààrin ìlú láti yí atí fi esè ètò

ìmulò, àti nínú èyí, àwọn ànfààní ìgbésè ará ìlú sarajọ fùn àsìkò.